Mrs. D.A. Fasoyin – Odun Nlo Sopin

Mrs. D.A. Fasoyin - Odun Nlo Sopin African Gospel
Play and Download
Download

Mrs. D.A. Fasoyin Odun Nlo Sopin MP3 Download

"Odun Nlo Sopin" is a song released in 1979 by Nigerian gospel artiste & lead singer of the renowned C.A.C. Good Women Choir, Ibadan Mrs. D.A. Fasoyin, from the album Odun Nlo Sopin.

With great recording effort, Mrs. D.A. Fasoyin on this throwback song titled "Odun Nlo Sopin" resulted in an astonishing display of skill, transforming it into an exceptional track.

DOWNLOAD:  Mrs. D.A. Fasoyin - Ara Mi Yio Ya Gaga

You are guaranteed to enjoy this awesome African Gospel hit by Mrs. D.A. Fasoyin which is also ready and available for download.

Odun Nlo Sopin Lyrics

Odun nlo s’opin o Baba rere
Baba maa so mi o t’omo t’omo
Ohun ti yoo pamilekun o L’odun titun
Maa jeko sele si mi o Baba rere [2X]

Maje n kawo leri sukun
Maje n faso ofo bora
Ogun rojuje rojumu, mama je ko je titemi
Alaafia pipe ni mo fe, fitamilore
Jenrina, jenrilo, Baba wa se milogo
Majentawona majentaraka lodun titun

Dabo Olorun mi dabo [2X]

Mama je kan f’ire temi s’apinle Mama je k’oro mi ja sofo lodo Re
Dabo Olorun mi dabo

Odun nlo s’opin o Baba rere
Baba maa so mi o t’omo t’omo
Ohun ti yoo pamilekun o L’odun titun
Maa jeko sele si mi o Baba rere

[Solo]
Baba Eleru niyin, wa suu’re fun wa
Ani kaa rona gbegba lodun to wole
Baba Eleru niyin, wa su’re fun wa
Ani kaa rona gbegba lodun to wole
Tuwon ninu, Oluwa tuwon ninu
Agan ti ko r’omo gbepon, tuwon ninu Oluwa
Rewonlekun Oluwa rewonlekun
Awon to dabii Hannah, tuwon ninu Oluwa

Odoodun lanr’orogbo, Odoodun lanr’awusa
Kodun ko san wa s’ owo, Kodun ko san s ‘ omo
Kaari batise, Kodun yaabo, Ka rona gbegba
Ani kama toroje, Ani kama toro mu
Kama l’akisa keyin aso, Baba gbo tiwa.

Kama se rogun ejo, Bawa segun aisan
Ogun asedanu, Ogun akoba, wa bawase
Abo re to daju lawa nfe, lodun to wole
Ohun rere to ye wa, Baba Fi se wa logooooo

Ohun ti yoo pawalekun o ninu odun,
Maa jeko sele si wa o Baba rere
Odun nlo s’opin o Baba rere
Baba maa so mi o t’omo t’omo,
Ohun ti yoo pamilekun o L’odun titun
Maa jeko sele si mi o Baba rere

Mp3 Music Download:

Solve the following math problem to download the music:

Download

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*